Ẹ ǹlẹ́ o,
Ẹ kúu dédé àsìkò yí. Nínú àròkó yìí a ó sọ̀rọ̀ ní ṣókí nípa àwọ̀ ní èdè Yorùbá àti ìtúmọ̀ wọn ní ède Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn nìyìí:
| Yoruba | English |
|---|---|
| Funfun | White/ Cream |
| Dúdú | Black / Dark colours |
| Pupa | Red / Bright colours |
| Ewéko | Green(ish) |
| Ewé | Green(ish) |
| Wúrà | Golden |
| Fàdákà | Silver |
| Igi | Brown |
| Ara | Brown |
| Búráùn | Brown |
| Aró | Blue |
| Búlúù | Blue |
| Elese àlùkò | Purple |
| Pọ́pù | Purple |
| Pupa fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ | Pink |
| Òféèfé | Orange |
| Omi ọsàn | Orange |
| Ìyèyè | Yellow |
| Pupa rúsúrúsú | Yellow |
| Yẹ́lò | Yellow |
| Eérú | Ash colour / Grey |
Ó dàbọ̀.