Àwọ̀ ní èdè Yorùbá

Ẹ ǹlẹ́ o,

Ẹ kúu dédé àsìkò yí. Nínú àròkó yìí a ó sọ̀rọ̀ ní ṣókí nípa àwọ̀ ní èdè Yorùbá àti ìtúmọ̀ wọn ní ède Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn nìyìí:

Yoruba English
Funfun White/ Cream
Dúdú Black / Dark colours
Pupa Red / Bright colours
Ewéko Green(ish)
Ewé Green(ish)
Wúrà Golden
Fàdákà Silver
Igi Brown
Ara Brown
Búráùn Brown
Aró Blue
Búlúù Blue
Elese àlùkò Purple
Pọ́pù Purple
Pupa fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ Pink
Òféèfé Orange
Omi ọsàn Orange
Ìyèyè Yellow
Pupa rúsúrúsú Yellow
Yẹ́lò Yellow
Eérú Ash colour / Grey

Ó dàbọ̀.